
Ile Lawa (Freestyle) Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Ah zoom zoom zoom
Ita lawa keh oti desu bayi
Ati fi gbogbo owo se December
Ramoni de sope kin rora ball
Mo ranju mo moni ko gbenu sohun
Lapo ti call mi wonipe kin dawo pada
Boya palmpay ninma ti yawo pada
Mo fowo je chicken (areeka)
Wonso funmi but meegba
Pastor toni 2023 lodun mi
Gari mo ma tun fi bere lodun yi
Tinba muyin peren ama ja pa
Ema je 4 si pari Ema gbapa
Enu ti gbe ile lawa (ile lawa)
Eyin omoba ile lawa (ile lawa)
A ti di introvert ile lawa (ile lawa)
Owo ti ku wazo ile lawa (ile lawa)
Ile lawa ile lawa (ile lawa)
Enu ti gbe ile lawa (ile lawa)
Eyin omoba ile lawa (ile lawa)
A ti di introvert ile lawa (ile lawa)
Owo ti ku wazo ile lawa (ile lawa)