Ọ̀JẸ̀JẸ̀ Lyrics
- Genre:Alternative
- Year of Release:2023
Lyrics
Eh
Eh
Ọ̀jè̩jè̩ Ọmọ nlá abara gẹgẹ
wọn ni o ma f'ínú w'énú ko ma ba jẹ iwọ
Osika i wi fun ni ijọ ohun o sekà
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩
Ah
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ o
Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ mi
Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni
Ẹni o se iwaju ẹni ko ma tun gbọdọ sẹyin ẹni
Aiye kòótó̩ ẹyin o suwọn ibi ori d'ani si la n gbe jaiye
Nigba to ń bẹ l'aiye ọrẹ mi wọn o le f'ẹjú fun ọ
Àkukọ kọ lẹyin ọmọkunrin wọn wa n sọrọ eniyan
Ọ̀jẹ̀jẹ̀ kilode t'aiye yi o gún mọ
Lagbaja lohun ọrẹ rẹ kori kosun ọrẹ kori kosun rẹ
Igba ti soro de ọrẹ na pápá bora
Igba t'ikú de wọn d'asọ ẹbi gbogbo aiye lo gbọ
Ẹjẹ ka se igba ile jẹjẹ a o mọ b'igba oko yio so bi o so
O dun la n j'ẹ̀fọ̀ ọrẹ wọn ni t'ile oge t'oge jẹ
Ọ̀jẹjẹ mọ mọ sọni barin oo
Ọ̀jẹjẹ oo sọni gbọkan rẹ le
Ẹbami p'ọ̀jẹ̀jẹ̀
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ o
Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ mi
Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni
Ọ̀jè̩jè̩ na my guy Ọ̀jè̩jè̩ na better person o
Ọ̀jè̩jè̩ na chop make i chop o make life for better
But no be when life better you go know your true friends Ọ̀jè̩jè̩
Dem go call you angel o when dem dey chop from you Ọ̀jè̩jè̩
Dem go call you nwanem o when dem dey eat from you Ọ̀jè̩jè̩
But when trouble come na then you go know your true friends Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jẹjẹ
Mọ mọ sọni barin oo
Ọ̀jẹjẹ oo
Sọni gbokan rẹ le
Ẹbami p'ọ̀jẹ̀jẹ̀
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ mi
Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Ọ̀jè̩jè̩ o o o o
Ọ̀jè̩jè̩ ooo
Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ mi
Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni
Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Eh Ọ̀jè̩jè̩ mi o
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Eh bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ ẹẹ
Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni
Wọn ni o ma fi inu wenu aiye nika
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Ọ̀jè̩jè̩ wọn ni o ma finu wenu ko ma ba jẹ iwọ Ọ̀jè̩jè̩
Ọ̀jè̩jè̩ o o awo mi ni
Ma finu wenu Ọ̀jè̩jè̩ eh eh eh
eh eh eh
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Sọni ba rin Ọ̀jè̩jè̩ mi
Ọ̀jè̩jè̩ o o
Ọ̀jè̩jè̩ ọmọ nla
ọmo nla
Ọ̀jè̩jè̩ o o awo mi ni
Ọmọ nla
Ah
Ọmo nla ma finu wenu
Aiye eh eh
Ọ̀jè̩jè̩ oooo
Aiye soro oh oh
Ma finu wenu ah
Ọ̀jè̩jè̩ oooo
Ọmọ nla Ọ̀jè̩jè̩
O ba ma finu wenu
Ọ̀jè̩jè̩ o o awo mi ni