![Ejo! ... Street Outro](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/56/2D/rBEeNFoS5iiABDgoAAER4O7R-30187.jpg)
Ejo! ... Street Outro Lyrics
- Genre:Afropop
- Year of Release:2009
Lyrics
Ejo o
Ejo o Ejo o
Otunba marose lon soro o
Otunba marose lon soro o
Obama tuntun gbogbo computer village lon soro o
Olu maintain loni kinyin sile o
Gbogbo eko
Gbogbo eko
Gbogbo team lagos
Olu maintain loni kiyin sile o
Lati ori sule authority baba oba gbogbo eko
Lori Mustapha say gbogbo eko
Lori small turaya
Lori orji turaya
Gbon kole si fadeyi
Olu maintain ni kin ki femi Jacobs
Obama gbogbo fadeyi
Obama gbogbo fadeyi
Oni nki otunba e
Kb fighter gbogbo fadeyi
Oni ke ba oun toju iyan daada
Ba kanle si mushin lodo toba
Olu maintain loni kin kiyin sile
Toba gbogbo mushin
Eyan olota wahabu
Ti ba kuro mushin
Bakanle si ilupeju lodo siroma gbogbo ilupeju
Light house gbogbo ilupeju
E toju ebony dada gbogbo bariga
Olu maintain loni kin kiyin sile o
Number one sola aku gbogbon team lagos
Ti ba kuro nbe ma kan le si Maryland
Lodo matthew gbogbo Maryland
Olu maintain loni kin kiyin sile o
Won ni ke toju killer dada
E toju legacy dada
Ti n ba kuronbe ma kan le si oshodi
Ma kan le si oshodi
Lodo Mc musiliu olu omo
Ko si oba loshodi
Olu omo lon wanbe
Olu maintain loni kin kiyin sile o
Ma tun kan le sodo koko saria
Koko saria
Otun olu omo
Olu maintain loni kin kiyin sile o
Won ni ke toju baba fela dada one dollar gbogbo oshodi
Ti n ba kuro n be
Ma lo si iyana ipaja obama gbogbo iyana ipaja
Tolani danger Olu maintain king of hip hop loni kin kiyin sile
Won ni ke teju original aboki dada
E toju play boy lateef dada
Ti n ba kuro n be olu agege
Ma kanle si odo aboki ameda
Aboki ameda gbogbo agege
Won ni ke teju ota nurudini
E toju agbede taju baba baba baba
Agbede taju baba baba baba
Ti n ba kuro n be ma tun lo ojota
Lodo olu omo stainless
Olu maintain king of hip hop loni kin kiyin sile
Won ni ke toju sule minister
E toju fola fine boy
Gbogbo neyin ti ikeja ati femi kuti
Olu loni kin kiyin sile
Uncle femi kuti se n gbo
Olu maintain lo ni kiyin
Sister yeni mama the mama se n gbo
Olu maintain lo ni kiyin
Gbogbo computer village lati ori number one
Otunba marose obama gbogbo computer village
Olu maintain lo ni kiyin sile
Dele enibalomo erikina gbogbo ikeja
Ebora gbogbo ikeja
Olu maintain lo ni kiyin o
Lori ajalu gbogbo ilu ikeja
One dollar
Lori alhaji lala
Olu maintain lo ni kiyin o
Omo ojiyamo latifu
Baba omo tun tun
Baba omo tun tun
Olu maintain lo ni kiyin sile o
Oni oku ewu omo
Lori mama atiku
Balogun gbogbo ilu ikeja
Lori odun saheedi
Otun oba lori segun dollar
Olu maintain lo kin yin sile
Ejo o Ejo o
E le light cigar nile epo
E le light cigar nile epo