![Alo Alo](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/03/9E/rBEeMlf7eYmAGpCMAAClcGuIzbA447.jpg)
Alo Alo Lyrics
- Genre:Afropop
- Year of Release:2016
Lyrics
Alo Alo - Olu maintain
...
Olú! Ṣé wọn ò tún ní sọ pé a sample báyìí
Shample kẹ̀! Ṣé eléyìí dún bi original létí ẹ ní?
Ó mà jọ
Oò mọ iye owó tí èèyàn fi book, tí èèyàn fi sanwó fún producer, kí na tún fẹ́ kí èèyàn ṣe? Eléyìí original tó
Kò matter, jẹ́ a ṣe wo, tó bá ti di...
Àlọ́, àlọ́ o. Àlọ́!
Àlọ́ o. Àlọ́!
Àlọ́, àlọ́ o. Àlọ́!
Àlọ́ o. Àlọ́!
Story, story o. Story!
Story o. Story!
Story, story o. Story!
Story o. Story!
E get one baby, em name na Democracy (democracy)
Naturally em get mummy and daddy (mummy and daddy)
Em papa name na, homer, Africa! (Africa)
Em mama name na (oh mama'a), mother, Nigeria! (Nigeria)
Since 1960, ask me wetin happen. (wetin happen?)
Na from one military takeover to another
As time dey go, ọmọdé ti dàgbà tán o
41 years still nothing to show o
Make I give you an example
Since 1985 coup, Maradona dabaru.
Look at dem dey dribble, to the left right, left right, left right, left
June 12 is a goal. Referee give MK red
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Ìyà yí le kú o, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Yorùbá ronú o, story, story, story
Hausa sai ki na e, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Nd'igbo mechi o, story, story, story
With BSc, no vacancy
Civil servant, no salary
Minimum wage, story
Standard of living, fallen
Fela talk am, em say;
"my people, suffering and smiling"
Na de thing
Common garri, nothing nothing
Commot for house for morning
You come reach for 8:30pm
Go-slow go come delay you
Ọ̀gá go give you query
Tó bá tún di ọjọ́ kejì
The same thing must to happen
Abeggi uncle Ṣẹ́gun
Kí ló dé ta ṣe ń jagun?
Ká tó rí epo
Wàá làágùn
40 Naira per litre
How manage? I wonder!
Everybody dey suffer
"Enough effizy" no longer
My brother, I taya
Left, right, left, right, left, right, left.
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Ìyà yí le kú o, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Yorùbá ronú o, story, story, story
Hausa sai ki na e, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Nd'igbo mechi o, story, story, story
Wọn má tí múná wá o
Ọpẹ o! Ibo ni máa tí wọlé báyìí?
Wọlé, tí space bá ti di, kó wọlé báyìí
40 Naira per litre
How manage? I wonder!
Everybody dey suffer
"Enough effizy" no longer
My brother, I taya
E no easy, palava
Left, right, left, right, left, right, left.
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Ìyà yí le kú o, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Yorùbá ronú o, story, story, story
Hausa sai ki na e, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Nd'igbo mechi o, story, story, story
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Ìyà yí le kú o, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Yorùbá ronú o, story, story, story
Hausa sai ki na e, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Nd'igbo mechi o, story, story, story
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Wọn jẹ́ Abiola ó ṣè'jọba tó fi kú o, àlọ́
A dúpẹ́ wọn gbé fún Obasanjo o, story
Ìyà yí le kú o, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Yorùbá ronú o, story, story, story
Hausa sai ki na e, àlọ́, àlọ́, àlọ́
Nd'igbo mechi o, story, story, story