The Mediator Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
The Mediator - Paul Tomisin
...
instrumentals
chants
look how far we've come
look at our people
look how far we've come
look how far we've gone
chants
Ile ola da woro ooo
chants
iya sun kun, igbe ekun Omo
Jeau
chants
ikunle abiaymo
e wo agba to see gbe
o da ilu ru kiri, o mu ti Kiri
Lai Shay elemu, Jesu
chants
e wo bi okunrin shan fi owo ko obirinnn, Jesu
chants
Shay aye ni ka pe eyi, Jesu
obirinnn bi okunrin, Okunrin bi obirinnn, Jesu
O si dakun ko gbo ebe wa
E wo tan pe si Jesu
E wo pastor to se se Omo ijo, Ko yato si babalawo
chants
E wo oselu ton se dari wa, ri wo ri wo
won na owo mekunu je, won na owo was je, Jesu
chants, tongues
ni gba ti ebi pa ara ilu, won se ni ma ko wo je.
E wo ton se pari wo jati jati bi eran ko
ni ilu ti ofin wa
ni ilu ti oba wa
ni gba ti ???
Si o Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re
A nko, Aleluya
chants
Si o Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re
A nko, Aleluya
Si o Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re
A nko, Aleluya
Si o Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re
A nko, Aleluya