Ancient Worship Medley ft. Dare Justified Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Ancient Worship Medley ft. Dare Justified - Paul Tomisin
...
I wo lo ni wa
Baba mode o ( jesu) aiye mi dowo re bami tun se
Sebi iwo lamokoko aiye mi ooo oluwa mo mi mo mi bo se fe
To ba mo mi aiye mi a lojutuu
To ba mo mi aiye mi a sun wo
Sebi wo lamokoko baba mo mi bi o ti fe
Oba ti n gbo Ekuñ aladura mo ti de(x2)
Gbe ja mi ja gbo ro mi ro ma je n gba gba nu Adura
I ro didun lorin seraph , oruko didun ni awon, Orin ti o dun julo ni jesu jesu jesu
Oloruko Aperire jesu oo ,oloruko apegbore jesu
Iwo ni olutunu orun fun ore ati agbara re a nko aa nko a nko Halleluyah
Halleluyah lo mumi goke modupe
Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu
Halleluyah lo mumi goke mo awon ota lowo
Halleluyah lo mumi goke odo
Cherunim e yoo
Seraphim e yoo
A fi ipinle le le lo ri o ti to
A fi ipinle le le lo ri ododo
Ipinle ti jesu fi Lele leyi ti baba aladura gbo mo duro le Christi apata
Gbo oun awon angeli ti n korin
Won korin ogo ogo
Won korin eye eye
Eri orun sokale ko wa gbe wa ro
Adaba Orun sokale mowa gbe wa wo
Ro ojo ibukun re le wa Lori
Le yin ipade wa yii jeka ri o ka to lo
Aa mo fe ri jesu ki n ma wo ju re kin na korin kin na wo ju re ninu ogo re kin gboun soke
A di ileri re mu pe wo yi o wa larin awa..awa ti o pejo loruko re
Emi mimo e se o emi awon wolii
Eyin kuku lagbara wa emimimo ese
Mo fara mo olorun babalola
Mo faramo olorun apostelii ona eyi ye mi o mo faramo olorun babalola
Ri n larin wa oluwa rin larin wa
Alagbara ma ni o o rin larin wa
Ija Dopin ogun ti tan olugbala jagun molu
Orin ayo la wa o ma ko Halleluyah
Halleluyah