Ladire (Soundtrack) Lyrics
- Genre:Soundtrack
- Year of Release:2023
Lyrics
Ladire (Soundtrack) - Abosede
...
Ko so omo na na
to le dena Ori
ko so omo na na
to le dena ese
ise de omo alaseje
owo de omo alasela
se bi ka ti ta
ka de ti kero eko dele o
Ladire
Ko so omo na na
to le dena Ori
ko so omo na na
to le dena ese
ise de omo alaseje
owo de omo alasela
se bi ka ti ta
ka de ti kero eko dele o
Ladire
se bi ka ti ta
ka de ti kero eko dele
Ladire
se bi ka ti ta
ka de ti kero eko dele
Ladire
bi ori ma de, ibi ori ma de
ese o gbodo pe ohun o lo
ati pe ko si, ko si aye fun aroye
asiko gan o pe ohun o lo
ba o ba re ni bala, re ni bala
ola i ya
ika kan o se fi gbaya, se fi gbaya
Ladire
ba o ba re ni bala, re ni bala
ola i ya
ika kan o se fi gbaya, se fi gbaya
Ladire
Te mi ye mi se mo mo
Ladire
Teni teni takisa ni ta tan
Ladire