Kumama Lyrics
- Genre:Folk
- Year of Release:2022
Lyrics
Kumama - Abosede
...
Mo ni baba kan Ooo
To mo iyi omo
ko ti e fi mi sere rara o
o mo Iyi mi
Olotunu mi lo je ninu gbogbo aala o
Awo gbaru ma gbeje
olu inu orun
Ah ato gbejule
Ah ato farati o
Oba adani magbagbe
eni oku ise oo
Eh yahweh eh yahweh kumama
LYRICS BY JOSHUA