- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Kirakita - Gbenga Beulah
...
Kirakita mi Laye yi Baba Ma jẹ o ja s'asan
Ọlọrun mo n bẹbẹ dakun Folakemi, ma ma jen fosilogba Baba wa dami Lola
Ati jeniyan eda láyé Lọwọ Ọlọrun lo wa
Àwon òhun t'ẹgbẹ mi nṣe ni rorun ma jẹ o nira fún
Jẹ mina o la kin ba won jeeniyan kín ṣe rere Elédùà
kirakita mi Laye yi Baba Ma jẹ o o jasasan Ọlọrun mo n bẹbẹ dakun Folakemi ma ma jen fosilogba Baba wa dami Lola
Oluwa dakun dabo ma jẹ n fosisaye óò
Baba Damilohun ma jen fosilogba o
Mo gbó jumi soke nibo niranwo síi yíò ti Baba
Baba Damilohun ma jen fosilogba o
see lyrics >>Similar Songs
More from Gbenga Beulah
Listen to Gbenga Beulah Kirakita MP3 song. Kirakita song from album Miracle Worker is released in 2024. The duration of song is 00:03:56. The song is sung by Gbenga Beulah.
Related Tags: Kirakita, Kirakita song, Kirakita MP3 song, Kirakita MP3, download Kirakita song, Kirakita song, Miracle Worker Kirakita song, Kirakita song by Gbenga Beulah, Kirakita song download, download Kirakita MP3 song