- Genre:Juju
- Year of Release:1981
Lyrics
Adetunji Adeyi - Chief Commander Ebenezer Obey
...
Èbá mi pe àdeyí o, Àdeyi owo. Àdeyí o, Àdeyí àtàtà. Àlágogo lekú-lekú Àbéyin àáro pelemó pelemó Àdeyí On ló sode o kàára ile àdeyí o, eeeh àdeyí òmó logbá logbá. Àrá oyo òmó òbá, Iseyin òmó òbá. Àrá oyo òmó òbá, Iseyin òmó òbá. Àrá oyo òmó òbá, Iseyin òmó òbá. Àrá oyo òmó òbá, Iseyin òmó òbá. Àládeyi motigbá, Motí bolúwá dúro. Àrá oyo òmó òbá Iseyin omo òbá. soyóyo Epo ìlá gbàrá ré lówó òbé. Were pe yárá re gbágí oko, Àládeyi gba àrá re lówó àáye. Epo ìlá gbàrá ré lówó òbé. Were pe yárá re gbágí oko. Àládeyi gba àrá re lówó àáye. Ìremi mobú tálágbéde nlé, Ìrení tí é. Àládeyi mí, Ìrení tí é. Bàbá àdeniran, ìrení tí é. Àládeyí mí, ìrení ni tí é. Baba adefunke, ìrení tí é. Àládeyi mi, ìrení tí e. Òkó adetayo, Òmó adeokú, Ìrení tí é. Àládeyi mí, ìrení tí é.
Similar Songs
More from Chief Commander Ebenezer Obey
Listen to Chief Commander Ebenezer Obey Adetunji Adeyi MP3 song. Adetunji Adeyi song from album Obey In The 60's Vol. II is released in 1981. The duration of song is 00:03:04. The song is sung by Chief Commander Ebenezer Obey.
Related Tags: Adetunji Adeyi, Adetunji Adeyi song, Adetunji Adeyi MP3 song, Adetunji Adeyi MP3, download Adetunji Adeyi song, Adetunji Adeyi song, Obey In The 60's Vol. II Adetunji Adeyi song, Adetunji Adeyi song by Chief Commander Ebenezer Obey, Adetunji Adeyi song download, download Adetunji Adeyi MP3 song