- Genre:Juju
- Year of Release:1981
Lyrics
Awon Alhaji - Chief Commander Ebenezer Obey
...
Músúlúmí to re meka to bo ko sope fún Òlúwá won ti meka de medina won lo wo ise iyanu won ti mecca de medina won lo wo ise iyanu Tábá jèyo tàba jé sékú ko si ohún to dàrá to Tábá jèyo tàba jé sékú ko si ohún to dàrá to Latí Jidá de medina kasolá re méká o Sanúolú re meka on bó o Sanúolú re meka on bó o Gbogbo àwón to n lo de medina Ìlé Sanúolú re meka on bó o Ero bámí ki àwon Alhaji ero bámí ki àwon Alhaja gbogbo Ero bámí ki àwon Alhaji ero bámí ki àwon Alhaja gbogbo ÌYÁ ÀLHÁJÁ Managing director òmó sanúolú òkó Alhaja ayoka òkó Alhaja asabi mi Bódùn ìleya bá de Èran pìpá ose pátákí fun àwon oni mále opo Alhaji lo san owo meka ti kolerá o je ko ló. opo Alhaja lo san owo meka ti kolerá o je ko ló. Mo na òwó mí soke kolerá màámá mú mi Mo na òwó mí soke kolerá màámá mú mi Àísan búbúrú kolerá màámá mú mí Mo na òwó mí soke kolerá màámá mú mi ìgbé gbúrúrú èébi yamiyami Mo na òwó mí soke kolerá màámá mú mi.
Similar Songs
More from Chief Commander Ebenezer Obey
Listen to Chief Commander Ebenezer Obey Awon Alhaji MP3 song. Awon Alhaji song from album Obey In The 60's Vol. II is released in 1981. The duration of song is 00:04:29. The song is sung by Chief Commander Ebenezer Obey.
Related Tags: Awon Alhaji, Awon Alhaji song, Awon Alhaji MP3 song, Awon Alhaji MP3, download Awon Alhaji song, Awon Alhaji song, Obey In The 60's Vol. II Awon Alhaji song, Awon Alhaji song by Chief Commander Ebenezer Obey, Awon Alhaji song download, download Awon Alhaji MP3 song
Comments (3)
New Comments(3)
Anikulapo Stephen
Taiwo Adeniyicgs2t
great great great great great great great great great great great great great great great great great great great great great great great
horlarsc671x
i like this
mo liki Orin yyi oooo