Messiah Oloruko Nla
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Messiah Oloruko Nla - The City Choir
...
Messiah, olórúkọ ńlá, Ológo dídán, kìnnìún ńlá, Ajẹ́-bí-iná, alágbára ńlá olùgbàlà, olùwòsan, olùgbé ja, olùgbanilà, Olùpèsè, paríparí ọlá, ọba àwọn ọba, aṣáájú ogun, akẹ́yìn ogun, ọba mímọ́, tó jẹ mímọ́, tó mu mímọ́, tó wọ mímọ́, to jókòó síbi mímọ́, mímọ́, mímọ́
Messiah, olórúkọ ńlá
Ológo dídán, kìnnìún ńlá, Ajẹ́-bí-iná, alágbára ńlá, olùgbàlà, olùwòsan, olùgbé ja, olùgbanilà, Olùpèsè, paríparí ọlá, ọba àwọn ọba, aṣáájú ogun, akẹ́yìn ogun, ọba mímọ́, tó jẹ mímọ́, tó mu mímọ́, tó wọ mímọ́, to jókòó síbi mímọ́, mímọ́, mímọ́ ọ ọ ọ
Messiah!
A déé Ọlọ́run mi Ọba mi àgbà!
Parí parí ola, porogodo ògo
Messiah
see lyrics >>Similar Songs
More from The City Choir
Listen to The City Choir Messiah Oloruko Nla MP3 song. Messiah Oloruko Nla song from album Messiah Oloruko Nla is released in 2024. The duration of song is 00:04:47. The song is sung by The City Choir.
Related Tags: Messiah Oloruko Nla, Messiah Oloruko Nla song, Messiah Oloruko Nla MP3 song, Messiah Oloruko Nla MP3, download Messiah Oloruko Nla song, Messiah Oloruko Nla song, Messiah Oloruko Nla Messiah Oloruko Nla song, Messiah Oloruko Nla song by The City Choir, Messiah Oloruko Nla song download, download Messiah Oloruko Nla MP3 song
Comments (3)
New Comments(3)
MacDonald 9eg2t
thmidayo
Love it and the beat
pretty dammy black
finally i got to see this song full of God's name and inspirational
Nice