Messiah Oloruko Nla Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Messiah Oloruko Nla - The City Choir
...
Messiah, olórúkọ ńlá, Ológo dídán, kìnnìún ńlá, Ajẹ́-bí-iná, alágbára ńlá olùgbàlà, olùwòsan, olùgbé ja, olùgbanilà, Olùpèsè, paríparí ọlá, ọba àwọn ọba, aṣáájú ogun, akẹ́yìn ogun, ọba mímọ́, tó jẹ mímọ́, tó mu mímọ́, tó wọ mímọ́, to jókòó síbi mímọ́, mímọ́, mímọ́
Messiah, olórúkọ ńlá
Ológo dídán, kìnnìún ńlá, Ajẹ́-bí-iná, alágbára ńlá, olùgbàlà, olùwòsan, olùgbé ja, olùgbanilà, Olùpèsè, paríparí ọlá, ọba àwọn ọba, aṣáájú ogun, akẹ́yìn ogun, ọba mímọ́, tó jẹ mímọ́, tó mu mímọ́, tó wọ mímọ́, to jókòó síbi mímọ́, mímọ́, mímọ́ ọ ọ ọ
Messiah!
A déé Ọlọ́run mi Ọba mi àgbà!
Parí parí ola, porogodo ògo
Messiah
Èmánúẹ́lì ọba tí a bí ooo
Mímọ́ mímọ́ nínú ọlá ńlá
Messiah
Ọba mi tó jẹ mímọ́ tó mu mímọ́ oo, tó fi mímọ́ bora bí aṣọ ooo
Messiah
Ẹrù jẹ̀jẹ̀ ẹrú jẹ̀jẹ̀, mímọ́ mímọ́ mímọ́ mímọ́ mímọ́ mímọ́
Ọ̀ bá ni lálejò wó hun tó nílé máa jẹ
Messiah
Ọba tó ń jẹ mímọ́, tó ń mú mímọ́ tó ń fi mímọ́ bora bí aṣọ, kìnnìún ńlá oooo
Messiah, olórúkọ ńlá, Ológo dídán, kìnnìún ńlá, Ajẹ́-bí-iná, alágbára ńlá, olùgbàlà, olùwòsan, olùgbé ja, olùgbanilà, Olùpèsè, paríparí ọlá, ọba àwọn ọba, aṣáájú ogun, akẹ́yìn ogun, ọba mímọ́, tó jẹ mímọ́, tó mu mímọ́, tó wọ mímọ́, to jókòó síbi mímọ́, mímọ́, mímọ́ ọọọ
Messiah
Kìnìún ńláaaa
Morí bá
Morí ì ba
Morí ìbà, baba mi Olórí ogun
Messiah!
Ẹrù jẹ̀jẹ̀, ó gbé ikú mì ní ìṣẹ́gun, baba mi ọ̀rọ̀gọ̀jigọ̀, baba mi ọ̀ bá ni lálejò wó hun tó nílé máa jẹ
Èmi ni ti ń jẹ́ ẹ̀mi ni, èmi ni ti ń jẹ́ èmi ni
Messiah
Òhun ni ọba aládé àlàáfíà, mímọ́ mímọ́ nínú ọlá ńlá, nínú ògo, óún gbé'nu múdíá ṣọlá, óún gbé' nu adélébọ̀ s'ògo, ẹlẹ́rù
Messiah
Èlẹ́rù n'iyì Ọba wa
Messiah, olórúkọ ńlá
Ológo dídán, kìnnìún ńlá, Ajẹ́-bí-iná, alágbára ńlá, olùgbàlà, olùwòsan, olùgbé ja, olùgbanilà, Olùpèsè, paríparí ọlá, ọba àwọn ọba, aṣáájú ogun, akẹ́yìn ogun, ọba mímọ́, tó jẹ mímọ́, tó mu mímọ́, tó wọ mímọ́, to jókòó síbi mímọ́, mímọ́, mímọ́ ọọọọ