![Ipile To Dara](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/04/14/ae2fe16496f14a788b5f4d3a357fece6_464_464.jpg)
Ipile To Dara
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2001
Lyrics
Eyin alase ti nbe lori alefa
Alefa ijoba leleka-njeka
Eyin ti nsisee 're
Ti nsise idagbasoke
Tilu ati ti gbogbo eniyan
Mo kiiyin e o saseye e o ni mosi kehin laye
Eyin tojepe ibi kobaje leyin nduro si
Ipade kobaje leyin nse kiri
Toje tara yin nikan leyin nja fun
Ojo esin yin tisu dede, ojo eleya yin kola
Sugbon ejeka fipile lele o, ipile to dara
see lyrics >>Similar Songs
More from Micho Ade
Listen to Micho Ade Ipile To Dara MP3 song. Ipile To Dara song from album Solid Foundation is released in 2001. The duration of song is 00:03:27. The song is sung by Micho Ade.
Related Tags: Ipile To Dara, Ipile To Dara song, Ipile To Dara MP3 song, Ipile To Dara MP3, download Ipile To Dara song, Ipile To Dara song, Solid Foundation Ipile To Dara song, Ipile To Dara song by Micho Ade, Ipile To Dara song download, download Ipile To Dara MP3 song