
OLORI IJO T'ORUN
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
OLORI IJO T'ORUN - OLUWALONIBISI
...
1. OLORI ijo t’ orun,
L’ ayo l’ a wole fun O;
K’ o to de, ijo t’ aiye,
Y’o ma korin bi t’ orun,
A gbe okan wa s’ oke,
N’ ireti t’ o n’ ibukun;
Awa kigbe, awa f’ iyin
F’ Olorun igbala wa.
2. Bi a wa ninu ‘ponju,
T’ a nkoja ninu ina,
see lyrics >>Similar Songs
More from OLUWALONIBISI
Listen to OLUWALONIBISI OLORI IJO T'ORUN MP3 song. OLORI IJO T'ORUN song from album YORUBA HYMN CLASSIC is released in 2024. The duration of song is 00:04:37. The song is sung by OLUWALONIBISI.
Related Tags: OLORI IJO T'ORUN, OLORI IJO T'ORUN song, OLORI IJO T'ORUN MP3 song, OLORI IJO T'ORUN MP3, download OLORI IJO T'ORUN song, OLORI IJO T'ORUN song, YORUBA HYMN CLASSIC OLORI IJO T'ORUN song, OLORI IJO T'ORUN song by OLUWALONIBISI, OLORI IJO T'ORUN song download, download OLORI IJO T'ORUN MP3 song
Comments (1)
New Comments(1)
ezzygold1boy
I love ❤️ this song