- Genre:Acoustic
- Year of Release:2023
Lyrics
Mafope fun o o baba mimo, aleluya modupe To ko mi yo ninu gbobgbo iji,o funmi layo mojo Ma f'ijo f'ayo f'oluwawa aleluya modupe, Mo wadupe ore kankan, ore gbangba O seun o.
Ninu ewu gbogbo o komiyo,ninu ibi gbogbo omumiye Ki lo tu yemi bi k'oseope, ma k'orin ayo, Ayo s'oluwa. Baba emi m'ore, opo loti ku o Opo lowa lewon, emi wa laye.
Mafope fun o o baba mimo, aleluya modupe To ko mi yo ninu gbobgbo iji,o funmi layo mojo Ma f'ijo f'ayo f'oluwawa aleluya modupe, Mo wadupe ore kankan, ore gbangba O seun o.
Ara e ebamiyo,
Oluwa ma lo somid'ala-yo, ebamiyo (e wa bami yo) Oluwati segun funmi Imota ti do fo lorimi ebamiyo (e wa bami yo). Ayo ore gbangba o seun o
Similar Songs
More from St. Cecilia Students' Choir, UI
Listen to St. Cecilia Students' Choir, UI Ma F'Ope MP3 song. Ma F'Ope song from album Songs of Praise is released in 2023. The duration of song is 00:05:02. The song is sung by St. Cecilia Students' Choir, UI.
Related Tags: Ma F'Ope, Ma F'Ope song, Ma F'Ope MP3 song, Ma F'Ope MP3, download Ma F'Ope song, Ma F'Ope song, Songs of Praise Ma F'Ope song, Ma F'Ope song by St. Cecilia Students' Choir, UI, Ma F'Ope song download, download Ma F'Ope MP3 song