Gbo Gbo Wa La Fine : A Letter To The Beauty Police (Sped Up) Lyrics
- Genre:Acoustic
- Year of Release:2022
Lyrics
Bi mo ba Kola
Se mo fine?
Bi mo ba Bula
Se mo fine?
Bi mo ba pupa
Se mo fine?
Bi mo ba sanra
Se mo fine?
Bi mo ba Dudu
Se mo fine?
Ti mo tun tiring
Se mo fine?
Ti ara mi o ba pe
Se mo fine?
Tin nkan nkan o ba to
Se mo fine?
Abi awon kan nikan ni
Ni kan ni
Abi awon kan nikan ni
Ni kan ni
Gbo gbo wa la fine
Gbo gbo wa la fine
Gbo gbo wa la fine
(You know i'm talking to you)
Gbo gbo wa la fine
Bi mo ba kere?
Se mo fine?
Ti mo really kere
Se mo fine?
Bi mo ba pelebe
Se mo fine?
Ti mio tie ni curve?
Se mo fine?
Bi mio ba nirun?
Se mo fine?
Ti mo ni desert
Se mo fine?
Bi mo ba je afin
Se mo fine?
Ti mo je rara
Se mo fine?
Abi awon kan nikan ni
Ni kan ni
Abi awon kan nikan ni
Ni kan ni
Gbo gbo wa la fine
(You know i'm talking to you)
Gbo gbo wa la fine
(You know i'm talking to you)
Gbo gbo wa la fine
(You know i'm talking to you)
Gbo gbo wa la fine
Gbo gbo wa la
Don't let your insecurity
Tie you to a spot
Don't let whatever Industry
Determine what you are worth
Don't let your insecurity
Tie you to a spot
Don't let whatever Industry
Determine what you are worth
Don't let your insecurity
Tie you to a spot
Don't let whatever Industry
Determine what you are worth
La fine
Gbo gbo wa la fine
Gbo gbo wa la fine
Gbo gbo wa la fine
Gbo gbo wa la fine