![KADOSH GBOGBONISE](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/08/16/ba23bcf6e3204b3a8d274dd86726f901_464_464.jpg)
KADOSH GBOGBONISE Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Call:- Asaph ti gbara de o
Resp:- ka lulu ka jijo ope ,s'eledua, ka korin ka yin baba logo.
Mimunu eledumare dun sha lo je wa login, awa n baba kan ni gbejo, oti se wa l'ayanfe, eyi ni majemu tada, Iwo yo ma jolorun a o ma jeniyan re Titi lailai
ka lulu ka jijo ope ,s'eledua, ka korin ka yin baba logo.