![Kala](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/07/19/b94c5e2d084549f69ed4bb282685faa1_464_464.jpg)
Kala Lyrics
- Genre:Afrobeat
- Year of Release:2022
Lyrics
Kala - ksbpepper
...
elimi
elijah aaaaa
ksb motunde eh
it's maxido the inspirational producer
àjọ bẹrẹ ní
àjọ bẹrẹ ní
ọwọ tẹ ekú ìdá
lobá fẹ yẹrí
má gbé ori sá rara
a óò mọ bí ọla ṣe mari
Ola lè pe jù
asé pé ènìyàn seku seye ní
eh eh eh
a jọ n tẹ ike ní
aa jo n tẹ ike ni
lo bá cashout
lóba fẹ yẹrí
eh eh eh eh
a óò mọ bí ọla ṣe mari
talo de mọ
ọrọ ọlọrun ṣebi ede ní
inú òní bí ajá Títí
kò lọ ibu lọ pà ẹja
kò lọ ibu lọ peja
Hennessy te gbójú lé
àti gbé àti já
àti já dànù
fifo loke sa Ni tí ẹyẹ
Atan kalẹ ní tí òsùmàrè
ọmọ arúgbó ooooo
Ajoke Ade
Ajoke Ade
arúgbó oooo ikeade
ọmọ tó rẹwa
happy birthday
happy birthday
happy birthday
happy birthday
wà dá gbà láyé
ikeade ikeade
ọmọ Nla Ni
adunloye
adunloye eh
ọmọ baale loje
Ajokeade
Ajoke Ade eh
Ajoke Ade eh
akalamagbo
èyí pá ọdún jẹ eh
loke loke
lemu n ru sí iii
lenu nrú si
àjọ bẹrẹ ní
àjọ bẹrẹ ní
ọwọ tẹ ekú ìdá
ló bá fẹ yẹrí
kò dá rárá
a óò mọ bí ọla ṣe mari
kò sí ẹni tó mọ
àṣe pé ènìyàn seku seye ní
èyán ibí ní se
a jọ hùn tẹ ike ní
aa jọ n teke ni
ló bá cashout
lóba fẹ yẹrí
eh eh eh
a óò mọ bí ọla ṣe mari
kò sí ẹni tó mọ
ọrọ ọlọrun ṣebi ede ní
ọmọ arúgbó tí dé
ọmọ arúgbó tí dé ooooo
Ajoke Ade
Ajoke Ade
ọmọ adunloye
ọmọ adunloye eh
happy birthday
happy birthday to you se
ọmọ arúgbó tí dé
ọmọ arúgbó tí dé ooooo
Ajoke Ade eh
ọmọ tó rẹwa
ọmọ adunloye
ọmọ adunloye eh
happy birthday
happy birthday
happy
bo ka'la mí
má ka'la eh
bo jẹ ojú mi
ma jẹ ojú eh
má jé ojú eh
from day one tí a tí hùn bọ
óò wá fẹ ka'la mí ní iseyin na oor
ah ah ah ah ah ah ah
mopelola
Aki wọn
temitope
aki wọn
baale adunloye
aki wọn
ajaratu
aki wọn
Moriamo
aki wọn
iremide
aki wọn
ayobami
àki wọn
oluwadarasimi
àki wọn
Dami dapper
àki wọn
ìyá àfín oo Omobolanle
àki wọn
samsondeen
àki wọn
ma crown
àki wọn
olarewaju
àki wọn
ọmowunmi Aduke mí
àki wọn
eba mí kí first lady
àki wọn
màmá T
àki wọn
tee Dynamics
aki wọn
aki wọn
àki wọn
KSB lórúko mi iiiii
lóba fẹ yẹrí