![Unchangeable Changer](https://source.boomplaymusic.com/group1/M0C/D7/06/rBEeMV2nHLiAOOCwAAC8Eie4j5I068.jpg)
Unchangeable Changer Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
Unchangeable Changer - Adegbodu Twins
...
Oba to kole ikan,fun kan o se
oba to ko teraa fun eraa o seun
Ohun lo forite sele eye
Iwo to mogo watan kakiri agbaye
Awa yio maa royin re kakiri agbaye
Omo adegbodu ati jajaye ati jajaye
Ati kogo aye jaa,(rept)
Ati jajaye ati kogo aye ja2x
Ko sohun to ku funwa bi oba sope
Ati jajaye ati kogo aye jaa