OLORUN LO YE Lyrics
- Genre:R&B
- Year of Release:2022
Lyrics
Ono ti omi gba de nu agbon
Olorun lo ye
Ojo a ro
Orun a ran
Ni bi kan ma
Ati lo ju kan na
Lo ju kan na
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Agbara to egbe jesu christi rin lo ri omi
Olorun lo ye
Elijah pe ina so ka le
La ti oke orun
La ti oke orun
Ta ba ni
Ta ba wi
Ko ma ye eni kan kan
Ko ma ye eni kan kan
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Bi ile se n shu
Ati bi ile se n mo
Olorun lo ye
Olorun lo ye
Adi tu Atu di
Ni olodumare