Ilahi Ose (Ilu Meccah, Medinah) Lyrics
- Genre:Holiday
- Year of Release:2012
Lyrics
Ilahi Ose (Ilu Meccah, Medinah) - Saoti Arewa
...
mase lekan feni toti lo
mmas leewo feni n jeran re( ilu mecca. mecca medina iroyin o tamoju ba modebe lo le so)
mase leekan feni toti lo kosi maje o jeewo feni jeran re o(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
***** modebe ri ero tan dabi omi mi o riru e ri a o tu leri otundi taa ba pada silu mecca o oh(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
no de kahaba ile oluwa won wo sibe ori rigindi
mo foju kan **** ile ase ohun toba so nibe kosiye meji o n lati se(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
safa marwa a n lati sa a o tawaf nile oluwa ekule ji eyan tori olohun ta o ma wa riri fun sati ramoni o oh(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
mo ki omo ibrahimo mo foju mi ri musdalifa lati sako ta o so fun esu fojo meta baba pelu mama tomo lo siketa o oh(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
An lati de minna fojo marun ni a o lo sarafa fojulowo ise olori ilu atawon alase o baa joloro tabo joba tolowo ti talika deede laje ninu ihram qul sawa sawa o(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
mosalasi anobi n be ni medina o ninu e naa ni rodotu n be mo de saare ta sin asaju aye si abubakri lo n be lowo otun umar losi a salamo siwon o ah(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
tosi anobi no baqqi n be egberun ogorun saabe Lo sun si maqbadatu sshuada iruhu asin awon toku sogun yoku si pelu hamza a salamo siwon **** mo debe kirun mode mosjidil qiflatayn oh(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
oke ti muhammad ti n gba quran o jabal nurr mo foju mi ri mosi tun bawon de jabal ramma oke ti won pe ni jabal toro istijaba nbe loke yen gbigbadura naa n pe be e mo rawo si allahu mo belohun nibe o(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
sabra ma's ad mosaasi meje ari a tun losi gogo ira atiwo tiwon le muhammad de towu alantakun basiri anobi o oh(ilu mecca mecca medina iroyin o tamojuba modebe lo le so)
Ni moseni omo tuntun ma lalaji tuntun
OMO tuntun ma lalaji tuntun
eni sise hajj pe o lese lorun o(omo tuntun ma lalaji tuntun)
adomo jojolo new born baby(omo tuntun ma lalaji tuntun)
Ema gbade anobi wole oti lo(omo tuntun ma lalaji tuntun)
Ema daari mecca doni paraga o(omo tuntun ma lalaji tuntun)
be o ronu owo e baa ronu wahala o(omo tuntun ma lalaji tuntun)
ESO alhaji alhaja leyin mecca(omo tuntun ma lalaji tuntun)
Ema fise sina e beru olohun(omo tuntun ma lalaji tuntun)
Ara tefi tawaf ile oluwa(omo tuntun ma lalaji tuntun)
e fara naa lowo nitoro anobi o(omo tuntun ma lalaji tuntun)
pansaga agbere n ba hajj je ni(omo tuntun ma lalaji tuntun)
alhaji to n paro o so hajj somi ni(omo tuntun ma lalaji tuntun)
alhaja to n jale fi hajj wole o(omo tuntun ma lalaji tuntun)
oju tori kahaba ile oluwa(omo tuntun ma lalaji tuntun)
emafi wo iwokuwo o dowo yin o(omo tuntun ma lalaji tuntun)
ESE tefi sa safa pelu marwa(omo tuntun ma lalaji tuntun)
emafi rin rin kurin o dowo yin o(omo tuntun ma lalaji tuntun)
alha
ji to soko pe pelu alhaja o(omo tuntun ma lalaji tuntun)
olohun ti ya e yesu ma fowo e wesu(omo tuntun ma lalaji tuntun)
mase hajj mi leekan soso
olohun oba mase hajj mi leekan soso
odoodun ma lowun mi alalo tunlo (mase hajj mi leekan soso)
odoodun ma lowun mi alalo tunlo(mase hajj mi leekan soso)
eje a jo sami eyin alarafa mi(mase hajj mi leekan soso)