Olori Oko ft. Kenny K'ore Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2018
Lyrics
Olori Oko ft. Kenny K'ore - Infinity
...
Hmnn I have seen the future
Though I am not a prophet, hn hnnn
In the book of Revelation
There is warning for the nations
He that has any ear let him hear
What the spirit is saying
Eh!!
Aisi n le olongbo (In the absense of the cat)
Loun mu eku sako (the mouse takes charge)
Yiyo tekun n yo (the Leopards's stalk for his prey)
Ki ma e se tojo (should not be mistaken for fear/cowardice)
Agba ki wa loja kori omo tutun wo (A child's head should not be badly moulded while there are elders in the market place)
Fitila yi to tan (Before the oil lamp burns out)
Imole wole wa (Let the light come in)
Imole ti de (Light has come!)
Eh!!
Olorioko shi n bo wa
On bo wa
On bo wa ye
Olorioko shi n bo wa
On bo wa
On bo wa ye
Olorioko shi n bo wa
On bo wa
On bo wa ye
Olorioko shi n bo wa
On bo wa
On bo wa ye
A fo pin ina
T'loun o pa fitila
Ara re ni opa
Se bi aaro to ba gbon eh
L'ogun aso tele ki ipa, aye egbo
Afoju di omo eniyan
Olohun Oba
Iku lon mu dani
Iye iye
Aisi n le olongbo
Loun n mu eku sako
Yiyo tekun n yo
Ki ma e se tojo
Agba ki wa loja
Kori omo tutun wo
Fitila yi to tan
Imole wole wa
Imole ti de
Eh!!
Aye ile, aye ile
Edumare baba
Edumare baba
Emura emura...
Emura emura
Ye ye ye ye ye
Aye ile, aye ile
Edumare baba
Edumare baba
Emura emura...
Emura emura
Olorioko nbo o
Jagunmolu nbo o
Papa nla ti n jo tohun tohun
Efufu ti mi le titi
E eh
Olorioko nbo o, emura
Oba a sa ya
Oba aidigbolu
Eni o digbolu o asi mu wo mu womu...