IGBE NI AIYE Lyrics
- Genre:R&B
- Year of Release:2022
Lyrics
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Bi a o je igbe
A le ya igbe
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Se inu igbe
Sha ni owo wa
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Bi a o je igbe
A o le ya igbe
Ibu eran sha ni won bi jesu christi si
Ti eran n ya igbe si ibe
Eran n tu to si ibe
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Bi a o je igbe
A o le ya igbe
Se owun a ba ra la ma ta
Se owun a ba je la o ya
Eni ti o fe ru n igbe
Ko le di eyan ra ra
Re ra re si le
Ki jesu Kristi
Gbe o ga
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Bi a o je igbe
A o le ya igbe
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Se inu igbe sha ni owo wa
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Bi a o je igbe
A o le ya igbe
Ile aiye ti awa yi
Ko le wa ko ma ni
A le nu Kan ra ra
Ile aiye ta wa ti
Ko si eni to pe
Jowo re ra re si ile
Ki jesu Kristi
Gbe o ga
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Bi a o je igbe
A o le ya igbe
Igbe ni aiye
La se n ya igbe
Se inu igbe she ni owo wa
Igbe ni aiye