![AGBA TI KIN N BINU](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/05/09/8525678bc5304279a42585ac7340b240_464_464.jpg)
AGBA TI KIN N BINU Lyrics
- Genre:R&B
- Year of Release:2022
Lyrics
Agba to ba wa ti o kin binu
Se bi owun ni omo re n po si
Agba to ba wa ti o kin binu
Se bi owun ni omo re n po si
A ri inu ma bi kan ko si
Ni aiye
Suru afori ti is what makes the difference
We should try to be alittle bit patient with another
We can make life to look alittle bit better with another
Jesu so ni inu iwe mimo
Do not let your anger lead you to sin
Agba to ba wa ti o kin binu
Se bi owun ni omo re n po si
Agba to ba wa ti o kin binu
Se bi owun ni omo re n po si
Ile ta ba fi suru ko
Ibinu o ma le ko rara
Ile ta ba fi suru ko
Ibinu kan o ma le ko rara
Patients and time is all that we need
Patient and time is all that will speak
Agba to ba wa ti o kin binu
Se bi owun ni omo re n po si