
Baba Mi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Baba mi
Apata aidigbolu
Irawo owuro
Jesu
Bi o ba wole
Imole a tan
Irawo owuro
Jesu o
You're the light that shines in darkness
You're the solid rock on which I stand
You're the one who gave me victory
Irawo owuro
Jesu o
iba o
Irawo owuro
iba o
Aya yi o pa awon alejo
Won afi iberu bo jo jade ni nu ko lo fin won
Ni to ri bi o ba wole
Imole atan si gbogbo wa
Bi oba wole imole atan si nu aye wa
Baba mi o wo kenbe re bi ja
Oromo ni se faya ti
Jagun jagun ode orun
Akobi ninu awon oku
Ogbe ni ni ja Ke ru o bo ni ja
Mo sun mo oba ni won egbefa
Mo ji na so oba ni won egbeje
Mo se kabiosi
Gbogbo eniya npe o ni gbigbe ga
Gbogbo ise da npe o ni gbigbe ga
Ka bio o si
Eye oju orun ko gbe yin
Wan npe o gbigbe ga
Ewe ori igi
Wan npe o gbigbe ga
Eja inu ibu
Wan npe o gbigbe ga baba mi o
Eran inu igbo
Wan npe o gbigbe ga
Tomode tagba
Wan npe o wan gbe npe o
Ni tori na, egbe ori yin soke
Eyin enu ona
Ki asi gbe yin soke eyin ilekun ayeraye
Nito ri oba ogo
Oba ogo ti wole wa
Ta ni oba ogo
Ta ni oba ogo yi
Jesu to le ni ipa ati agba ra
Ni oba ogo
Iba iba iba
Oruko Jesu
Ile iso agbara ni
We reference you