Mo Fe Gbo Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Mo Fe Gbo - Oluwatosindoz
...
My eyes are lifted up
To you lori Oro aye mi;
Ko ye mi, Baba wa gbo mi o e;
My ears are open, Lord to you
I'm waiting patiently
Olutosona mi, mo wa gbohun re;
Orisirisi ohun lo wa laye yi;
Sugbon tire nikan ni mofe ma gbo;
I wanna hear you
Come Father draw near;
Save me, with thy powerful right hand!
Mofegbo o, to ba n bami soro;
Ye Oluwa, Mofegbo o
Mofegbo o, to ba n bami soro;
Ye Oluwa, Mofegbo o
Along the way of life I tred;
I wanna walk as you direct
All my steps, Ona ti n ma to lo;
And when I walk along the way
My heart is open, Lord
To know what to do;
Oluwa ma je n subu;
O sa ti mope, o je Olutoju mi;
Ko tu senikan ti mole sa to lo;
I know you'll never leave me;
Nor forsake me
Let your word Apprehend my heart!
Mofegbo o, to ba n bami soro;
Ye Oluwa, Mofegbo o
Mofegbo o, to ba n bami soro;
Ye Oluwa, Mofegbo o
Oro itunu, The word that comforts me;
Oro Ife, the word of Love that never fails;
Oro iye yi, the word I wanna hear;
Jesu, Oluwa mi o, wa bami soro!
Call: Baba soro kin gbo, Oluwa soro
Resp: Soro kin gbo, Oluwa soro!