Iya ni Wura Lyrics
- Genre:Alternative
- Year of Release:2022
Lyrics
Iya ni Wura - Dipo Sodipo
...
Iyaniwura, baba ni jigi
Iyaniwura baba ni jigi
Ijo iya ku ni wura ola baje
Ijo baba ku ni jigi eni womi
ijo iya ku ni wura ola baje
Ijo baba ku ni jigi eni womi
Iyaniwura, baba ni jigi
Iyaniwura baba ni jigi
Ijo iya ku ni wura ola baje
Ijo baba ku ni jigi eni womi
ijo iya ku ni wura ola baje
Ijo baba ku ni jigi eni womi
boba lowoo toju iya re loto
boba lola o, fitun baba rese
koranti aisun iya lorire o
kotoju bi baba se n sare kiri
Iyaniwura, baba ni jigi
Iyaniwura baba ni jigi
Ijo iya baku ni wura ola baje
Ijoti baba ku ni jigi eni womi
ijo iya ku ni wura ola baje o
Ijoti baba ku ni jigi eni womi
boba lowoo fitun mama re se
boba lola, fitun obi rese
koranti aisun iya lorire o
koranti bi baba se n sare kiri
ranti ranti ranti ranti aisun iya lorire o
ko ranti bi baba se n sare kiri