
Nipa Ife Olugbala Lyrics
- Genre:Pop
- Year of Release:2021
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
Nipa Ife Olugbala - Oyeyemi Sweet-Melody
...
Nipa ife olugbala,
Ki y’o si nkan;
Oju rere Re ki pada
Ki y‘o si nkan;
Owon 'leje t’o wo wa San;
Pipe l’edidi ore ofe
Agbara lowo to gba ni
Ko le si nkan.
Bi a wa ninu iponju,
Ki y’o si nkan;
Igbala kikun ni tiwa,
Ki y’o si nkan;
Igbekele Olorun dun;
Gbigbe inu kristi lere
Emi si nso wa di mimo,
Ko le si nkan.
Ojo ola yio dara,
Ki y‘o si nkan,
`Gbagbo le korin ninu 'ponju
Ki y’o si nkan;
Agbekele ’fe Baba wa ;
Jesu nfun wa l’ohun gbogbo
Ni yiye tabi ni kiku;
Ko le si nkan.(Amin)