MajeNri Ft. Mr Gbera Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
MajeNri Ft. Mr Gbera - Min. Femi A. Owolabi
...
Olorun Maje
Olorun magbe bami majenri
mi ofe mi ofe
Ogun kawolori
fesejanle
maje nri ri RI
Majenri
majenri
ògún kawoleri
feseja lẹ
majenri
owurọ mi
osàn mi àti alè
majen pàdà f'ori balẹ forisa ooooo
Majenri
majenri
ògún kawoleri
feseja lẹ
majenri
owurọ mi
osàn mi àti alè
majen pàdà f'ori balẹ forisa ooooo
Moti bẹrẹ Dàda laye bí
Majẹ subú
maje ṣiṣe
maje ṣiṣe láyé mi
Don't let me fall
Don't let me fail
Di mi mu dopin majenribi
ogun airi na
majenri
ogun afa to
majenri
oogun aitegbe
majenri
ogun gbese
majenri
lodun Titun
losu titun nigba gbogbo
majen riiiiii ooooo
Majenri
majenri
ògún kawoleri
feseja lẹ
majenri
owurọ mi
osàn mi àti alè
majen pàdà f'ori balẹ forisa ooooo
majenri
Majenri
majenri
ògún kawoleri
feseja lẹ
majenri
owurọ mi
osàn mi àti alè
majen pàdà f'ori balẹ forisa ooooo
ire ni tan Yan
gbogbo ibi kúrò lọnà mi
mo gb'adura kan dami mon
ọba oke sign soro mi
ire topo fi bamilo
idamu ma gbe bami
oti gba aṣọ iya lara mi
oti gbà aṣọ osi lara mi
kana mi ma dá joni lọ
ma jọba lo majenribi
eeeeeeh
ire gbogbo loju owo ri
kaye mi ko dun
igba mi ko dun kalẹ
ọlọrun Maje
ọlọrun magbe bami
majenri
llori iṣẹ mi baba
majenribi
lori aya lori ọmọ
majenribi
ibi korimi sa laye mbi
majenribi
oti gbaso iya lara mi
lori ebi lori ara oooo
majenribi
majenribi laye Ti mo wà popo
lori ẹgbọn lori aburo
majenribi
lori omo lori iṣẹ Ọlọrun
majenribi
arinakore akoya ibi layemi
majenribi majenribi
majenribi
back to sender
majenribi
arikeybson production