![Mo wa yin o Logo (Have come to praise you)](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/10/13/b8e7ff6928f64b69a909b2128206b014.jpg)
Mo wa yin o Logo (Have come to praise you) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Mo wa yin o Logo (Have come to praise you) - Omotayo Adepitan
...
Efi ope fun Oluwa awon oluwa
nitori ti o seun
nitori ti anu re duro lai lai
nitori ti anu re ooo duro Lai Lai
Ogun orun bami yin ooo pe esee
Ogun orun bami yin ooo pe ese
(beat)
mo wa yin oo logo fun fe reee si mi oo
mo wa yin oo logo fun anu re si mi
mo wa yin oo logo fun fe reee si mi oo
mo wa yin oo logo fun anu re si mi
(beat)
meloo ni ka ro ninu ore re ooo
meloo ni ka so ninu agbara re ooo
meloo ni ka ro yin ninu ise iyanu re
meloo ni ka so ninu agbara re ooo
oba to pa wa moo to dawa si do ni oo
baba alabo wa oo awa yin o ooo
mo wa yin logo fun fe re si mi ooo
mo wa yin ooo logo fun anu re simi