Rin Ile Mi Koja ft. Asaphs Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2019
Lyrics
Rin Ile Mi Koja ft. Asaphs - Ejire Aditu Ogo
...
RIN ILE MI KOJA lyrics by Ejire Aditu Ogo. chorus.
Rin ile mi koja ki aiye lemo pe iwoni, so agbegbe mi di NLA kinye rin ninu ise o, ati iya baba banse o, ngo lelomiran, Rin ile mi koja o, Kaye lemo pe iwo ni. *2.
verse1
ba mi se olorun ayo fi oni ba mi se o,
bi ori ba pe ni ile sebi a di ire ni o,
aini ti to o,
olorun fi oni se opin iya yi,
ba mi se olorun iyanu,
rinkoja, chorus. Rin ile mi koja ki aiye lemo pe iwoni, so agbegbe mi di NLA kinye rin ninu ise o, ati iya baba banse o, ngo lelomiran, Rin ile mi koja o, Kaye lemo pe iwo ni.
Verse 2
okan ti Oyò fi ese te afara oyin
Okan ti ebi Npa ohun gbogbo kikoro LOduN lenu won
Okan a se aisan bi ileri o ba Tete se
Mu okan mi kuro Ni tubu ki ara mi leyin ó logo
(Bi onami basu ohun losan tomi
Kisa gboron sa ohun yio si pese )2ce
Bi ran lowo eda gbogbo ba saki
oro ti enu re so yiobori dandan
Aigbagbo bila temi Sha loluwa ohun yio si dide fun iranwo mi
Isoro malo temi ma lo lorun ohun yio si dide fun igbala mi
Kinsama gbadura ohun yio se iranwo
Gba krist wa lodo mi ifoya kosi. baba ban se o nho lelomiran se, rin ile Mi kojao Kaye lemope iwo ni, rin koja. chorus. Rin ile mi koja ki aiye lemo pe iwoni, so agbegbe mi di NLA kinye rin ninu ise o, ati iya baba banse o, ngo lelomiran, Rin ile mi koja o, Kaye lemo pe iwo ni.
Verse 3
wan ni otun ti de esofun pe mi o sinle o,
awin lowawa ko ma fi tie kobami,
ola a da lon tenu mo o,
doni aho ri iyato rara,
iwo to da mi dasi oro ayemi o,
ahofe jeun ota ore ko odana ko fun ni je,
bi aban yawo ka olorun ojokan ni ete a de o,
pa ete re o olorun fi oni se opin iya yi, rin ile Mi koja o, Kaye lemo pe iwo ni rin koja.
chorus. Rin ile mi koja ki aiye lemo pe iwoni, so agbegbe mi di NLA kinye rin ninu ise o, ati iya baba banse o, ngo lelomiran, Rin ile mi koja o, Kaye lemo pe iwo ni.
verse 4
egbo, eda le lowo ki ifokanbale je aini fun,
otunle lola ki alafia je aini fun,
ole je aini oko o,
tabi aini aya ati omo,
iwo to dami dasi oro aiye mi o,
rinkoja.chorus. Rin ile mi koja ki aiye lemo pe iwoni, so agbegbe mi di NLA kinye rin ninu ise o, ati iya baba banse o, ngo lelomiran, Rin ile mi koja o, Kaye lemo pe iwo ni.
Verse 5
Opo obi longbaru ki omo bale kawe ni,
Pelu igbagbo pe bi omo ba kawe tan adara
Omo kawe óhun tan,
Korise se baba mimo,
Obio lagbara mo doni Aru Ni wonse Kiri .chorus. Rin ile mi koja ki aiye lemo pe iwoni, so agbegbe mi di NLA kinye rin ninu ise o, ati iya baba banse o, ngo lelomiran, Rin ile mi koja o, Kaye lemo pe iwo ni.
verse 6
ah, opo lon gbe bi oba lorile ede won,
won wa bi yiose dara de oke okun won gbe bi eru,
won jeun bi eru baba,
iwe igbelu di ohun inira fun won,
tete gba fun won, kan le pada sebi oba, omo oba niwon chorus. Rin ile mi koja ki aiye lemo pe iwoni, so agbegbe mi di NLA kinye rin ninu ise o, ati iya baba banse o, ngo lelomiran, Rin ile mi koja o, Kaye lemo pe iwo ni. Adlibs and chorus repeat. ojo nlo asiko nlo, Baba banse o, nho lelomiran, rin ile mi koja o, kaye le mo pe iwo ni. Hee, ojo ori eda onisuru bi eni, iwe oniwasu lofiyemi, okurin talakakan wa ni ilukan o, ohun fi ogbon re tun iluse, sugbon won rantire mo o, tori aini OLORUN se temi, ojo nlo asiko nlo igba nlo se o, OLORUN mio hee, temi ogbodo gbe nle aiye araye ti momi mo o eee, bori bape nle adire, imura aya ti eniyan imuse oro ti OLORUN ni, oro timo so gbo o, fasesi gbo o, fasesi gbooo, jekogoke orun wa OLORUN mi, ani imura aya ti eniyan ihmuse re ti OLORUN ni, gbogbo eti tongbo OLORUN se o, se funmi, se fun won, se fun won se fun mioo, se oooo