
Ara E Dide Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Ara E Dide - Dupe Olulana
...
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ninu ewu gbogbo o pa mi mọ
Ninu ewu gbogbo o mu mi ye
Ki lo tun yẹ mi bi ko se ọpẹ
Ọpẹ ni temi lọjọ gbogbo
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Owa fi ire gbogbo da mi lọla
otun fi ohun rere to tun ga ju
ki lo to yẹ mi bi kose ọpẹ
ọpẹ ni temi lọjọ gbogbo
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
otun fi ọmọ rere da mi lọla
otun fi ohun rere to tun ga ju
ki lo tun yẹ mi bi ko se ọpẹ
ọpẹ ni temi lọjọ gbogbo
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
ofẹ gbogbo wa d'oju iku
omu gbogbo wa dele ayọ
ki lo tun ye wa bi ko ṣe ọpẹ
ọpẹ iyin ni f'oluwa wa
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
ofẹ gbogbo wa d'oju iku
omu gbogbo wa dele ayọ
ki lo tun ye wa bi ko ṣe ọpẹ
ọpẹ iyin ni f'oluwa wa
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
oluwa mi lo gbe mi ga oo
oluwa mi lo gbe mi ga.
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ara ẹ dide ẹ ba mi jo
Eniyan mi ẹ ba mi yọ.
Oluwa mi lo gbe mi ga
Ẹru jẹjẹ baba ifẹ
oluwa mi lo gbe mi ga
Ẹru jẹjẹ baba ifẹ
oluwa mi lo gbe mi ga
Jesu mi lo ma ma gbe mi ga oo
oluwa mi lo gbe mi ga
atofarati baba ose
oluwa mi lo gbe mi ga
ọlọrun ikẹ baba mimọ
oluwa mi lo