Jesu N Gbo Adura Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Jesu yi n gbo adura mi o, o n gbo
Oba ogo n gbo adura mi o, o n gbo
Oro oluwa ko ni lo laise
Oro oluwa ko ni lo laise
Beere, a o fi fun o
Wa kiri, eyin o si ri
Kan 'kun, a o si si le fun yin
Baba lo le se ohun gbogbo
Mo wa, lati dupe o
Ope, atokan wa
Jowo je ki, ope mi d'odo re
Ki erin mi le po, jaburata
Baba lo le se ohun gbogbo
Jesu yi n gbo adura mi o, o n gbo
Oba ogo n gbo adura mi o, o n gbo
Oro oluwa ko ni lo laise
Oro oluwa ko ni lo laise
Oba to ji Lasaru dide
O gbo ti Hanna
O gbo ti Jabezi
O gbo ti Namani
O wo obinrin, onisu eje San
O wo awon, adete san
Baba lo le se ohun gbogbo
Ekun, oko faraho
Eleti, gbohun gbaroye
O so oloriburuku, d'olorire
O wo okan, oni rele san
Baba lo le se ohun gbogbo
Jesu yi n gbo adura mi o, o n gbo
Oba ogo n gbo adura mi o, o n gbo
Oro oluwa ko ni lo laise
Oro oluwa ko ni lo laise
Oro baba mi yo se titi aye o
Oro oluwa ko ni lo lai se
O gbe oro re ga ju oruko re lo
Oro oluwa ko ni lo lai se
Ni pa oro lo fi da ile aye o
Oro oluwa ko ni lo la se
Egungun gbigbe o da alaye o
Oro oluwa ko ni lo laisee