
THE EXPERIENCE (IRIRI) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
THE EXPERIENCE (IRIRI) - Omotola Jayeola (Mr Gbera)
...
mori ooo mori oo
morigba ooo
morigba oo
ah moranu gba Ni
moranu gba ni
ibi ti mo gba koja
awon kan gba be soda
onje ton Mara mi Dan
lawonko jeh temi bo
oun gbogbo to je baba ra fun won
lofi shara fun emi
Tori moranu gba Ni
iru iriri timori lawon kan ri
sugbon Anu Timo ri gba won ko rigba
ebi pamiri olorun mi ooo
sugbon ko pada jasi iku
aisan shey mi ri
olorun ko pada ja si iku
moronu olorun mi ooo
sugbon ko pada ja si ku
Moran ti gbese ojosi
olorun ko pada ja si iku
moranti accident ojo yen baami
olorun ko pada jah si iku
operation tokoja olorun
olorun mi kopada jasi iku
awon kan Ori fifo lasan Ori fifo lo son pe opariwo loro won fi pada wa jasi iku
won Ni Inu riro lon pariwo ton fi pada jasi iku operation tiwon se lojosi sebi owo wo gbo oo ma Ni oo (owo wo gbo ma Ni oo)
Ati iiya ati omo ati owo kosi eni to pada wale
oun gbogbo ton se mi olorun mi ooo awon elomiran ton se won o si laye mo..AHHH
iru iriri timori lawon kan ri
sugbon Anu ti mori gba won Kori gba
awon kan leshin Ni Keke si be won pada ku so kun
emi o Ni eshin Ni Keke mori ogun pada wa segun
konga mi to gbe won letan lomu aiye me to
iya aiye mi ana pada di iyanu modupe
ibi ti mogba koja (ibi ti mohba koja olorun)
lawon kan gba be soda (lawon kan gba be soda)
ounje to Mara mi dan (ounje to Mara mi Dan oooo )
lawon kan je te mi bo(emi won lobo)
oun gbogbo to je babara fun won
lo fi se ara Fe mi( ara lo fi se ee Fe mi)
Tori mo raanu gba Ni
iru iriri timori lawon kan ri
sugbon anu ti mori gba won Kori gba