
Àánu Rè Ni (It's His Mercy) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2019
Lyrics
Àánu Rè Ni (It's His Mercy) - Victor Anjorin
...
Eeeee e wa bami yo
Mo re Aanu gba aanu tosi mi
Yes i know i don't merit your mercy
Se be se nbe
Mo re aanu gba.
Nigba ti mo pa de alaanu
To fi aanu wa mi re to si ona mi ni ire
O se olu toju mi
O se adani ma gbagbe eni
O se eni ti o fi aanu femi
O se eni ti o mo mi
Eeeee e wa bami yo
Mo re Aanu gba aanu tosi mi
Yes i know i don't merit your mercy
Se be se nbe
Mo re aanu gba.
O ti ni o ma se aanu fun eni to ma se aanu fun
Hmmm o fi aanu wa mi re
Beeni mo pe ko tosi mi sogbun
Baba fi aanu gba mi
Olu fi aanu kemi ooo
Eeee wa ba mi yo
Eeeee e wa bami yo
Mo re Aanu gba aanu tosi mi
Yes i know i don't merit your mercy
Se be se nbe
Mo re aanu gba.
Aanu Re ni ooo
Aanu Re ni
Aanu Re ni ooo
Lo gbemi ro
Aanu Re ni oo
Aanu Re ni
Aanu Re ni ooo
Lo di mi mu.
Aanu Re ni ooo
Aanu Re ni
Aanu Re ni ooo
Lo gbemi ro
Aanu Re ni oo
Aanu Re ni
Aanu Re ni ooo
Lo di mi mu.
Aanu Re ni ooo
Aanu Re ni
Aanu Re ni ooo
Lo gbemi ro
Aanu Re ni oo
Aanu Re ni
Aanu Re ni ooo
Lo di mi mu.
Aanu Re ni ooo
Aanu Re ni
Aanu Re ni ooo
Lo gbemi ro
Aanu Re ni oo
Aanu Re ni
Aanu Re ni ooo
Lo di mi mu.