![Ogb'enutan (It's Mouth Widening)](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/10/15/403489468c46457790cc727d40b3396f.jpg)
Ogb'enutan (It's Mouth Widening) Lyrics
- Genre:Traditional
- Year of Release:2020
Lyrics
Ogb'enutan (It's Mouth Widening) - Toluwani
...
chorus:ogbenutan olorun mi ma tobi yeye
ogbenutan eleda mi ma kojasiso
kose royin iyanu eyi koja oye
ibi to bayemi de eyi jomiloju gidigan
pe Omo talaka Le joba pelomoalade
leader: ogbenutan olorun mi ma tobi yeye
ogbenutan ooeleda mima koja so
kose royin o iyanu eyi koja oye
ibi to bayemi de eyi jomiloju gidigan
pe Omo talaka Le joba pelomo alade
(back to ogbenutan)
solo1: ojomiloju alagbawi ma tayemise
esuju Anu wo mi afi bi eniwipe eminikanni
miracles everywhere bienipe Mon sodun ni
baba olu orun lofi ope mi damu ologbon
to mo mo talaka lo joba pelomo alade
(back to ogbenutan)
lead: to ba de everywhere
all:iwoni
lead : ninu ilemi
all:iwoni
lead: enini Jesu
all: olohun gbogbo
lead : pharoh se gbe
all:sinu okun
lead: isreal mi loooooo
all: egbominira nla(2 times)
back to ogbenutan olorun ( end)