![Eyin Agba](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/08/22/f52fa02464364c4fa3b1901d53746636H3000W3000_464_464.jpg)
Eyin Agba Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2000
Lyrics
Eyin Agba - Musiliu Haruna Ishola
...
Moti mari Faye ki n to tile wa. Moti seba lodo awon agba ooo, eyin agba e je o just see, eyin agba oo ooyee eyin agba teba ri pe a seyin, ema rojo wa sibi to soro omo yin laje ogbon oo dee bikan, omo yin laje ogbon oo dee bikan kan