Alagbara Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2020
Lyrics
Alagbara - Anny
...
Alágbára
By Anny
Alágbára l'Ọlorun mi
Alágbára l'Ọlorun re
Alágbára l'Ọlorun mi
Alágbára l'oruko re
Chorus:
{Titi aye ni ngo yin Ọ
Titi aye ni ngo sin Ọ Titi aye ni ngo yin Ọ Alágbára l'Ọlorun mi}
. .. ....
If I'm to sing of all You've done
And if I have a thousand tongues
It'll never be enough
Yeah...yeah
The times and places that You've showed up
I never thought I'll make it through
But You've made a way for me! Yeah, ah
Papa You never ever fail o
You never let me down
You're always by side, yeah yeah
The times and places that You've showed up
I never thought I'll make it through
But You have made a way for me, eh
Chorus:
{Titi aye ni ngo yin Ọ, Titi aye ni ngo sin Ọ, Titi aye ni ngo yin Ọ
Alágbára l'Ọlorun mi} X2
.. ..... .......
Elohim You are Mighty man in battle Papa
Only You are God
Only You are God over everything
Agunechemba
Bàbá mi mo ké aleluya!
Lord we bow to You
You are good
You reign in all the earth
Papa!!!!
Everyday I glorify Your name
My heart will sing You have done what no one else can do
Agunechemba ('chemba)
Bàbá mi mo ké aleluya!
Lord we bow to You
You are good
You reign in all the earth
Chorus:
{Titi aye (hahaha) ni ngo yin Ọ (wooh) , Titi aye (aye) ni ngo sin Ọ (ma sin Ọ), Titi aye (haha) ni ngo yin Ọ
Alágbára l'Ọlorun mi}
{Titi aye (aye) ni ngo yin Ọ (ma yin Ọ Baba) , Titi aye (aye) ni ngo sin Ọ (ma sin Ọ), Titi aye (aye) ni ngo yin Ọ
Alágbára l'Ọlorun mi}
{Titi aye ni ngo yin Ọ, Titi aye ni ngo sin Ọ, Titi aye ni ngo yin Ọ
Alágbára l'Ọlorun mi}
.....
Sync & extracted by: @summerslarm