
Iyanu Oro Olorun Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Iyanu Oro Olorun - EmmaOMG
...
Iyanu oro Olorun
Ni fitila fun ese mi
Imole si ipa ona mi
Emi Orun joluko mi
ni Ile eko ojo isinmi oni, Ko mi Oluwa,
Iyanu oro Olorun
Ni fitila fun ese mi
Imole si ipa ona mi
Emi Orun joluko mi
ni Ile eko ojo isinmi oni, Ko mi Oluwa
Komi Jesu, L'otito re
Si mi ni iye, Oluwa mi
Jowo fi Oro re yemi
komi ke'mi le je tire
Iyanu oro Olorun
Ni fitila fun ese mi
Imole si ipa ona mi
Emi Orun joluko mi (Jesu)
ni Ile eko ojo isinmi oni, Ko mi Oluwa,
Komi Jesu, ni Ona re
Ke'mi mase tun sako lo
Jowo gbami lowo ese
komi ke'mi le je tire
Iyanu oro Olorun
Ni fitila fun ese mi
Imole si ipa ona mi
Emi Orun joluko mi
ni Ile eko ojo isinmi oni, Ko mi Oluwa
Komi Jesu, je kin sunmo o
kin tubo sun mo odo re
Kin ba O rin lojojumo
komi ke'mi le je tire
Iyanu oro Olorun
Ni fitila fun ese mi
Imole si ipa ona mi
Emi Orun joluko mi (Emi Mimo)
ni Ile eko ojo isinmi oni, Ko mi Oluwa
Komi Jesu, Kin mo'fe Re
Kin se Ife Re lojojumo
Kin fi Ife Re han elomin
komi ke'mi le je tire
Iyanu oro Olorun
Ni fitila fun ese mi
Imole si ipa ona mi
Emi Orun joluko mi
ni Ile eko ojo isinmi oni, Ko mi Oluwa
Emi Orun joluko mi
ni Ile eko ojo isinmi oni, Ko mi Oluwa