![Owo Dollar ft. Obesere](https://source.boomplaymusic.com/group1/M1C/02/70/rBEeMV56KCWADbxPAADvk0jRUKA509.jpg)
Owo Dollar ft. Obesere Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2020
Lyrics
Owo Dollar ft. Obesere - Seriki
...
Intro (Abase Akande)
By fire by force we must shine (seriki )
Obesere ati seriki lowa ninu ogba yii
Won leni Kan n gbemu
Ta lon gbemu?
She e mo bi won she n nawo ni?
chorus (Abass Akande & seriki)
owo dollar lo n na (lo n na)
aso dollar lo n wo (lo n wo)
ounje dollar lo n je
at the same time (igbe dollar lo n ya)
owo dollar lo n na (lo n na)
aso dollar lo n wo (lo n wo)
ounje dollar lo n je
at the same time (igbe dollar lo n ya)
Verse 2 (seriki)
seriki omo owo ( o n ya dollar)
IBD dende ( o n ya dollar)
hushpuppi ( o n ya dollar)
Deji Tinubu ( o n ya dollar)
M.C oluomo ( o n ya dollar)
Niyass ( o n ya dollar)
Wale bouncer ( o n ya dollar)
Alhaji Abass Akande ( o n ya dollar)
See, bami pe dolapo ko maa bo
ko WA gbo nkan ti mo babo
To ba de ti n bo ko pelabo
Tori laleyi o maa konsolijapo
o sha ti ri, awon ti mo ba to
omo pe Bentley on she egbe Prado
Fine girl, obrigado
Ma lo bawon gbenu si kolorado
bi mo she n bosu mo ma n wonder
ma wule laagun jina, ma bother
wo, nkan to ba fe je ni ko order
omo gbagbe pe eeyan kan ti lo ti border
eni, eji, eta nkan te she se mo pe koda
e fun mi lorobo e mu lepa
orobo ke! agbara mi o ka
Chorus (Abass Akande & seriki)
owo dollar lo n na (lo n na)
aso dollar lo n wo (lo n wo)
ounje dollar lo n je
at the same time (igbe dollar lo n ya)
owo dollar lo n na (lo n na)
aso dollar lo n wo (lo n wo)
ounje dollar lo n je
at the same time (igbe dollar lo n ya)
Verse 2 (Seriki)
Wale Alagbon (o n ya dollar)
Godfather ( o n ya dollar)
Aremo Oniru ( o n ya dollar)
Baddy Osha ( o n ya dollar)
Abu Abel ( o n ya dollar)
Dammy Richie ( o n ya dollar)
Oba Bombay( o n ya dollar)
Alhaji Abass Akande ( o n ya dollar)
owo mo wa na mi o wa ya photo
mi o wa ya photo
seriki o wale o de yoo jo
o ni wale, o de ni yoo jo
see, aa ni payan, owo la maa pa
yee maa wo bi omoge she yapa
won wo bikini o,tun wo kaba
e ma pa baba oni baba
a n soro hard currency
make I dey eat your work honestly
e gbegbe ti gbegbe
gbe sumo mi kin fowo kan bebe
fine girl, unanugo
owo wa n le ma lo dami duro
coronavirus o kin pamugbo
Ma lo deru kinni nla barugbo
Chorus (Abass Akande & seriki)
owo dollar lo n na (lo n na)
aso dollar lo n wo (lo n wo)
ounje dollar lo n je
at the same time (igbe dollar lo n ya)
owo dollar lo n na (lo n na)
aso dollar lo n wo (lo n wo)
ounje dollar lo n je
at the same time (igbe dollar lo n ya)
Baakole (o n ya dollar)
hundred percent ( o n ya dollar)
obafemi martins ( o n ya dollar)
Tejumola Jerry ( o n ya dollar)
Idris perpay ( o n ya dollar)
Ade Benz ( o n ya dollar)
Kolawole edun ( o n ya dollar)
Alhaji Abass Akande ( o n ya dollar)
o n ya dollar
o n ya dollar
o n ya dollar
o n ya dollar (till end)