
Olori Ijo Torun Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2020
Lyrics
Olori Ijo Torun - Olamide Adeniyi
...
Olori ijo torun
Layo la wole fun O;
K'O to de ijo t'aye
Y'o ma korin bi torun
A gbe okan wa soke
Nireti to nibukun
Awa kigbe, awa fiyin
F'Olorun igbala wa.
Bi a wa ninu 'ponju,
T'a n koja ninu ina,
Orin ife lawa o ko
Ti yoo mu wa sun mo O
Awa sape, a si yo
Ninu ojurere Re
Ife to so wa di tire
Yoo pa wa mo titi lai.
Iwo mu awon eeyan Re
Koja isan idanwo
A ki o beru wahala
'Tori O wa nitosi
Aye, ese at'Esu,
Koju ija si wa lasan
Lagbara Re a o segun
A o si korin Mose.
Awa figbagbo rogo
T'O n fe lati fi wa si
A kegan ere aye
Ti a fi siwaju wa
Bi o ba si ka wa ye
Awa pelu Stefen t'o ku
Yoo ri O bo ti duro
Lati pe wa lo sorun