
JESU L’OJO ANU YI Lyrics
- Genre:Spirituals
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
JESU L’OJO ANU YI - Temidayo Oladehin
...
1. JESU, l'ọjọ anu yi
Ki akoko to kọja
A wole ni ekun wa.
2. Oluwa, m'ẹkun gbọn wa
Fi ẹru kun aiya wa
Ki ọjọ iku to de.
3. Tu Ẹmi Rẹ s'ọkan wa
L'ẹnu ọna Rẹ la nke
K'ilẹ kun anu to se.
4. Tori waiya-ija Reẹ
Tori ogun-ẹjẹ Rẹ
Tori iku Rẹ fun wa.
5. Tor'ẹkun kikoro Rẹ
Lori Jerusalemu
Ma je ka gan ifẹ Rẹ.
6. Iwọ Onidajọ wa
Ghat'oju wa ba ri Ọ
Fun wa n'ipo lọdọ rẹ.
7. Ìfẹ Rẹ l'a simi le
N'ile wa l'oke l'a o mọ
B'ifẹ na ti tobi to. Amin