Eleduwa Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2024
Lyrics
Eleduwa - Barry Jhay
...
Intro...
ojo buruku lonisotun'un.... !!!
baba sho'n gbo oun aiye'n so..
eledua.. eyin ni akoko ninu gbogbo nkan
keto da aye ati orun.
and that na why me I put you first in everything I do!!
o'ma ma se olorun mi...
opo opo ooo!!!!
chorus..
ibi tan ni ki gbegbe magbe, lofi shey apartey
ibi tan ni ki tete màté lò ló shey vacey
nigba tan tu wa'n soro, woni mio mo ju'olorun lo
baba sho'ngbo oun aiye so....
ayun lo, ayun bo lowo yun enu
iko o'ni ko bàlà mi lè sé... ni ola olorun
la tio ni lo, ki onaa mi kola peregede
la to ni lo, magbe ori ile yii seun rere..
Verse..
eyin to laye!!
e gbo oun mi se ase IFA... abiyamo aiye!!
e duro timi ki'n mase jabo oo...
ikoko lafi de'e!!! lodo IFA ooo
karaye mafowo bo agogo mi lenu ee!!
ti'n ba lu se ni koma dun'n...!!!!
(chorus.)
ibi tan ni ki gbegbe magbe, lofi shey apartey
ibi tan ni ki tete màté lò ló shey vacey
nigba tan tu wa'n soro, woni mio mo ju'olorun lo
baba sho'ngbo oun aiye so....
ayun lo, ayun bo lowo yun enu
iko o'ni ko bàlà mi lè sé... ni ola olorun
la tio ni lo, ki onaa mi kola peregede
la to ni lo, magbe ori ile yii seun rere..!!!!
la tio ni lo, ki onaa mi kola peregede
la to ni lo, magbe ori ile yii seun rere...