Owuro Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Òwúrọ̀ l'ọjọ́ ẹni má ríré o
Ẹni má ríré o
Nwa ṣe bà òwúrọ̀ ọ
Òwúrọ̀ l'ọjọ́ ẹni má ríré o
Ẹni má ríré o
Nwa ṣe bà òwúrọ̀ ọ
Ahh
Òwúrọ̀ mí a dára
Ọsàn mí a sunwọ̀n
Ìrè mí a bá mi kalẹ
Òwúrọ̀ mí a dára aa
Ayọ mí nbọ
Àṣẹ yìí a mọ̀ mi kalẹ
Ahh
B'ẹ̀mi bá wà ìrètí n'bẹ
B'ìrè bá wọlé ayọ̀ nì óò pin káári o ahh
Ojú ọrún t'ẹyẹ fò láì f'ará kànrá
Máa rí témi ṣe o
Máa rí témi ṣe o
Ọnẹ burúkú ọnẹ bruja
Ọnẹ kọnẹ má yà lé wá o
Ọnẹ burúkú ọnẹ bruja
Ọnẹ kọnẹ má yà lé wá oo