
Jesu Oba Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2012
Lyrics
Jesu oba
Iwo oba awon oba
Ibere ati opin
Kinihun awon eya Judea
Itan shon irawo owuro
Jesu oba
Iwo oba awon oba
Ibere ati opin
Oun gbogbo
Kinihun awon eya Judea
Itan shon irawo owuro
Agbe o ga
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ologo ju lo
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ayo aye
Aye yi o
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ologo ju lo
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ayo aye
Oluwa iwo lon joba lo
Eru jeje leti okun pupa
Talo le gbono woju oluwa
Tio ni beru
Ko tun se aferi re
Oluwa iwo lon joba lo
Eru jeje leti okun pupa
Talo le gbono woju oluwa
Tio ni beru
Ko tun se aferi re
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ologo ju lo
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ayo aye
Ayo aye yi
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ologo ju lo
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ayo aye
Mo gbe o ga bami o
Agbe o ga
Eru jeje leti okun pupa
A fori bale
Iwo ni
Ologo ju lo
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ayo aye
Mono mono oju orun
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ologo ju lo
Mo gbe o ga bami
Agbe o ga
A fori bale
Iwo ni
Ayo aye