![Ore](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/0B/A3/rBEeMlhSbBGAWsTMAADSIrBa36Y005.jpg)
Ore Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2010
Lyrics
Ma ya lé mi iwo orè atojubo onilé
Ma ya lé mi iwo orè agbok'oloko
Ma ya lé mi iwo orè adugbo
Ma ya lé mi ma ya lé k'omo
Orè ti mo mu bi aburo
Orè, orè ti mo sé daara dara
Orè ti mo fi nu hun
Owa daami o tumi sita
Odabi oro ano
Bi oro ano
Don't come to my house,
Iwo orè éké adugbo
Don't come to my house,
Iwo orè adaléru
Maya lé mi, iwo orè kofeniferé
Maya lé mio maya lé rara
Isè ni mo wa lojo yi o
Oko t'o fèmi si lè
Ko ku lo wa sè sé
La won mejéji, won bèrè isé kusé
Won wuwa omodé, won sé bose wun won
Odabi oro ano
Bi oro ano
Odabi oro ano
Bi oro ano
Ewa wo ija lo jo yen
Ewa wo éro ton tu ta
Ewa wo ejé ni le
Ah ore ore o o tu mi sita
Ma ya le mi o
I don't want to see you no more
Ma ya le mi o
Ma ya le mi o
I don't want to see you no more ore
Isé ku sé kun owo rè
Emi o ti ele pa eyan