
Gbope Mi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Amazing are things
You've done for me
You alone deserve
This grateful heart
Ese o
Ese o
Ese o
Mo wa yin ọ o Baba
I can't deny the truth
That you've been there
Here I am and all I've to say
Ese o
Ese o
Ese o
Mo wa yin ọ o Baba
Gb'ope mi Oluwa
Gb'ope mi Oluwa
F'ohun tẹ ṣe laye mi o
Ẹṣe o
Mo wa yin ọ o Baba
Gb'ope mi Oluwa
Gb'ope mi Oluwa
F'ohun tẹ ṣe laye mi o
Ẹṣe o
Mo wa yin o o Baba
Amazing are things
You've done for me
You alone deserve
This grateful heart
Ese o
Ese o
Ese o
Mo wa yin o o Baba
I can't deny the truth
That you've been there
Here I am and all I've to say
Ese o
Ese o
Ese o
Mo wa yin o o Baba
Gb'ope mi Oluwa
Gb'ope mi Oluwa
F'ohun te se laye mi o
Ẹṣe o mo wa yin o o Baba
Gb'ope mi Oluwa
Gb'ope mi Oluwa
F'ohun te se laye mi o
Ẹṣe o
Mo wa yin ọ o Baba
Baba mo juba
Mo m'orin ọpẹ wa
Eledumare eleburu ikẹ
Fun're tẹ se laye mi o
Kini n ba ṣe
Mo wa yin o o
Baba
Baba mo juba
Mo m'orin ọpẹ wa
Eledumare eleburu ikẹ
Fun're tẹ se laye mi o
Kíni n ba ṣe
Mo wa yin ọ o
Baba
Baba mo juba
Mo m'orin ọpẹ wa
Eledumare eleburu ikẹ
Fun're tẹ se laye mi o
Kíni n ba ṣe
Mo wa yin ọ o
Baba
Baba mo juba
Mo m'orin ọpẹ wa
Eledumare eleburu ikẹ
Fun're tẹ se laye mi o
Kíni n ba ṣe
Mo wa yin ọ o
Baba
Kini n ba ṣe
Mo wa yin ọ o
Baba
Kini n ba ṣe
Kini n ba ṣe
Kini n ba ṣe
Mo wa yin ọ o
Baba