KERESIMESI Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
(it's Femi Odewole and the guitar band again)
(merry Christmas and happy new year in advance)
Many years ago, ni ilu Bethlehem
25th December o, a bi Jesu oba wa
Without a doctor o, without a nurse o o o
Ninu otutu, lati bi jesu oba wa
Emmanuel ti de o, Merry Christmas gbogbo wa
Shebi ninu manger, lati bi Jesu oba wa
Emmanuel ti de o, Merry Christmas gbogbo wa
Ninu manger, lati bi Jesu oba wa
Keresimesi o (odun de)
Omo Maria de o (odun de)
Angeli wo n korin o (odun de)
Jesu omo Olorun (odun de)
Joseph the carpenter o (odun de)
Loko Maria yii o (odun de)
Oyun emi mimo o (odun de)
L'afi bi Jesu Kristi (oba wa)
Irawo nla yo l'okere, ati bi Jesu oba wa
Awon amoye meta won to Jesu wa, oba wa
Igbala ti de, iye ti de, Merry Christmas gbogbo wa
Omo Maria de o, oba wa
Irawo nla yo l'okere, ati bi Jesu oba wa
Awon amoye meta won to Jesu wa, oba wa
Igbala ti de, iye ti de, Merry Christmas gbogbo wa
Omo Maria de o, oba wa
Keresimesi o (odun de)
Omo Maria de o (odun de)
Angeli wo n korin o (odun de)
Jesu omo Olorun (odun de)
Joseph the carpenter o (odun de)
Loko Maria yii o (odun de)
Oyun emi mimo o (odun de)
L'afi bi Jesu Kristi (oba wa)
(it's Femi Odewole on the guitar band again)