Kekere Lyrics
- Genre:Hip Hop & Rap
- Year of Release:2009
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
Kekere - Dagrin
...
Won fe sere, won sope mo kere
Won ma fe invite mi ke
Won ma sare, ah!
Won ni were, oo
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Won tun ti de, еmi mofe sanjo, emi mofe sanjo, bi Obasanjo
Kon sе iro, eni ti o ba ra iro kole ra oto, kati mo ibi to to gba kade mo ona t'oto
Mo nsako tori mo l'awon orin to yii lowo
Bi opolo se n sako niwaju elegusi o da
Gbogbo wa lafe je dollar, patapat ka wa lo se lodo mallam, taba kowo yen de, kawa ma f'owo yen cha-cha
In short, gbogbo wa la fe, di millionaire
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Monday, Tuesday and Wednesday, Thursday
Titi di ojo jimoh, olowo laye mo, mo ni mo fe jemo
Oluwa se mi lolowo, eni ba lomo
Mi o ti lowo, won ti nsare gbe rumour, itumo?
Abi e dayan mo? Mo ti de, eti gbere, ok
Womi dada, komo bimo se je, duala, biko, ejo talombe?
Sukusuku bambam, eni t'oba wu ko be
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Emi to je pe, mi o n woju, Uche, fi le, gbasibe
Aunty, bobo oya ki o ko mole, bere mole
Mi o ni ki o boso sile, ma wo bose po to, won tobe, ok!
Toba jebe, e f'oro sile, move your body, body, shake your body, body
Move to the dance floor
Sugbon malo fi agbari gbari, ko gba'gidi, ko gba giri-giri, talon gbemu?
Baba oni waheed, I'm sorry, I'm in a hurry, don't worry
Mi o gbori, emi len sori?
A ki n ja kung fu but a je fufu, a nje dundu, a den, mu kunu, olun!
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were, were, were, were
Won sope mo kere, kekekere labere kere
Awon to jepe won le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won mag mere